Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá
Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá di ìrọ̀rùn ní Ilé Ẹ̀kọ́ Yorùbá:
Start
Learning
Language For
Free
Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá di ìrọ̀rùn ní Ilé Ẹ̀kọ́ Yorùbá:
Àṣà Yorùbá dùn, ó kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọgbọ́n, ó si ṣeé fi yangàn. Ó wù Olúwákẹ́mi ati àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ kí àwọn ọmọdé òde òní ní òye èdè Yorùbá kikà, kíkọ, àti sísọ yékéyéké ní ó mú kí wón gbé “Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá di ìrọ̀rùn” jade. Ninu eto yi ni kilaasi kíkọ , kikà ati sísọ ede Yorùbá wà ni www.protokospublishersonline.com tÍ ẹníkẹ́ni le darapọ̀ mọ́. Olúwákẹ́mi sì ti kọ àwọn ìwe Yorùbá miràn ti o le ran olùkọ́, òbí ati àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ́wọ́. Ẹ tún leèri àwọn ìwé wọ̀nyíí ni favouronline.kemiolaojo.com
